Altcoins Talks - Cryptocurrency Forum
Local => Nigerian Languages => Topic started by: okstefen on December 09, 2017, 06:04:46 PM
-
Yoruba ronu. Kini a le jumose lati so owo-eyo di Owo NLA?
-
Owo Eyo-Ayelukara... Lori A fefe
-
8) ;D Oyinbo to nso yoruba! Oba Alayelua, Oni ile ife a gbo si
-
Oyinbo ko ni eleyi o.. O ti di yoruba pon be le. He needs to be reported to ooni indeed :D ;D ;D
-
eyin omo Odua kilode? E jowo e jeki a gbawopo so ikanni Yoruba yi di gbajumo. Ri i daju wipe, o fi owo si ki o si fi ohun si pelu. Te atejise re si ibi ki Yoruba le di itewogba
-
Yes it's like dbx